Download Èdè hindi Bitcoin Sticker Files

Àfàànì wa ni láti ràn ọ́ ló́wó́ láti mú ènìyàn díẹ̀ síì mọ̀ Bitcoin nípà fífi àmì àlèmó́ Bitcoin sí ibì gbangba. Gbogbo àwọn àmì àlèmó́ wa ní kóódù QR tó so mó́ àwọn ojú-ìwé ẹ̀kó̀ nípa Bitcoin & owó ṣíṣé.

Tí o bá gbé ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tàbí Kánádà, o lè béèrè àkójọpọ̀ kan ti àwọn àlèmọ́ Èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ọ̀fẹ́.

Àlèmọ́ "Bitcoin Doesn't Have Inflation" (Osan)

Àlèmọ́ "Bitcoin Doesn't Have Inflation" (Osan)
  • Ìwọn: 21.59 sm x 4.6482 sm (8.5 ìnṣì x 1.83 ìnṣì)
  • Ohun-èlò: àmì àlèmó́ vinyl fún lílò ló́òdè
  • Ibì títẹ̀: A ń lo StickerMule.com ṣùgbọ́n o lè lo ilé-iṣẹ́ àlèmọ́ èyíkéyìí.

Àlèmọ́ "Bitcoin Doesn't Have Inflation" (Dúdú)

Àlèmọ́ Bitcoin "Cure Inflation"

Àlèmọ́ Bitcoin "Cure Inflation"
  • Ìwọn: 6.35 sm x 12.7 sm (2.5 ìnṣì x 5 ìnṣì)
  • Irú: àmì àlèmó́ tí a gé
  • Ohun-èlò: àmì àlèmó́ vinyl fún lílò ló́òdè
  • Ibì títẹ̀: A ń lo StickerMule.com ṣùgbọ́n o lè lo ilé-iṣẹ́ àlèmọ́ èyíkéyìí.

Àlèmọ́ Bitcoin "Got Inflation?"

Àlèmọ́ Bitcoin "Got Inflation?"
  • Ìwọn: 7.9248 sm x 14.605 sm (3.12 ìnṣì x 5.75 ìnṣì)
  • Ohun-èlò: àmì àlèmó́ vinyl fún lílò ló́òdè
  • Ibì títẹ̀: A ń lo StickerMule.com ṣùgbọ́n o lè lo ilé-iṣẹ́ àlèmọ́ èyíkéyìí.

Àwọn àbá àlèmọ́

Lẹ́yìn tí o ti tẹ àwọn àlèmọ́ rẹ, fi wọ́n sí ibi tí a yóò rí wọn! Àwọn ibi rere fún àlèmọ́ ni:

  • ní gbangba níbi tí àwọn ènìyàn yóò rí wọn
  • ní àwọn ibi tí kò ṣeé ṣe láti yọ̀ wọ́n kúrò ní kíákíá (àwọn àlèmọ́ kò fa ìbàjẹ́ títí láé)
  • lórí àwọn ojú tí wọn yóò sopọ̀ mọ́ ní rírọrùn (irin, pílástíìkì, gíláàsì)
  • KÌ Í ṢE lórí ohun-ìní àdáni, lórí àwọn àmì, ATM, tàbí àwọn ẹ̀rọ epo