Tẹ àti fi àwọn ìpolówó Bitcoin sí
Àwọn ìpolówó Bitcoin ọ̀fẹ́, tí a lè tẹ̀. Fi wọ́n sí gbangba láti ràn àwọn ènìyàn púpọ̀ síi lọ́wọ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Bitcoin.

Bí a ṣe ń tẹ̀ tí a sì ń fi àwọn ìpolówó Bitcoin yìí ránṣẹ́
Àfàànì wa ni láti ràn ọ́ ló́wó́ láti mú ènìyàn díẹ̀ síì mọ̀ Bitcoin nípà fífi ìwé pílàńkì Bitcoin sí ibì gbangba. Ìwé pílàńkì yìí ní kóódù QR tó so mó́ ojú-ìwé ẹ̀kó̀ Bitcoin wa.
Tẹ̀ ìwé pílàńkì yìí ní ilé tàbí ní ilé títẹ̀. Léyìn náà, fi sí lórí pákó́ ìṣẹ́, àwọn òpó owó erò ibanisọ̀rọ̀ àdúg¹bò ilú, àti àwọn ibì gbangba mìràn tí ènìyàn lè rí í kí wọn sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Bitcoin.
Lakoko tí o bá ń ṣe, bèèrè fún àkójọ àwọn àmì àlèmó́ Bitcoin òfẹ́ẹ́ wa láti mú kí ènìyàn díẹ̀ síì mọ̀ Bitcoin.
PIN ÀWỌN IBÌ ÌWÉ PÍLÀŃKÌ RẸ
Pin àwọn ibì ìwé pílàńkì rẹ pẹ̀lú wa lórí Nostr kí o sì rí ibì tí àwọn ènìyàn mìràn ń fi ìwé pílàńkì wọn sí.
Tẹ̀lé wa lórí Nostr nípà wíwá hi@bitcoin.rocks nínú àpù Nostr kaǹkaǹ.