Tẹ àwọn àlèmọ́ Bitcoin tirẹ pẹ̀lú àwọn àkójọpọ̀ àlèmọ́ Bitcoin yìí.
Àfàànì wa ni láti ràn ọ́ ló́wó́ láti mú ènìyàn díẹ̀ síì mọ̀ Bitcoin nípà fífi àmì àlèmó́ Bitcoin sí ibì gbangba. Gbogbo àwọn àmì àlèmó́ wa ní kóódù QR tó so mó́ àwọn ojú-ìwé ẹ̀kó̀ nípa Bitcoin & owó ṣíṣé.
Tí o bá gbé ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tàbí Kánádà, o lè béèrè àkójọpọ̀ kan.
O lè kópa nípà títẹ̀ àwọn àmì àlèmó́ tirẹ, láì ń ṣe àní ibì tí o wà! Tẹ̀ èdè rẹ nísàlẹ̀ láti gba àwọn fáìlì àmì àlèmó́ & àwọn ì̀tó̀sọ́nà.
Jọ̀wọ́: kìí ṣe gbogbo àmì àlèmó́ ni ó wà ní gbogbo èdè.